-
A translation of “If” by Rudyard Kipling to Yoruba.
Read more: A translation of “If” by Rudyard Kipling to Yoruba.Translated to Yoruba by Olanrewaju AJidagba Ti ó bá lè mọ́ kàn, tó o si bínú Nígbà tí àwọn tó wà ní sàkání rẹ bá n dá ẹ́ lẹjọ Nítorí pé wọn n Sojo Tí ó bá lè nígbagbọ́ nínú ará rẹ, báyé bá tiẹ síyè méjì Ṣugbọ́n ó Fàyè sílẹ fún ìyè méjì wọn…